Psalms 10:4 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Eniyan burúkú kò wá Ọlọrun, nítorí ìgbéraga ọkàn rẹ̀, kò tilẹ̀ sí ààyè fún Ọlọrun ninu gbogbo ìrònú rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Enia buburu, nipa igberaga oju rẹ̀, kò fẹ ṣe afẹri Ọlọrun: Ọlọrun kò si ni gbogbo ironu rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ènìyàn búburú kò lè rí i nínú ìgbéraga Rẹ̀; kò sí àyè fún Ọlọ́run nínú gbogbo èrò Rẹ̀;