Psalms 10:5 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà gbogbo ni nǹkan ń dára fún un. Ìdájọ́ rẹ, Ọlọrun, ga pupọ, ó ju òye rẹ̀ lọ; ó ń yọ ṣùtì ètè sí gbogbo àwọn ọ̀tá rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọ̀na rẹ̀ nlọ siwaju nigbagbogbo; idajọ rẹ jina rere kuro li oju rẹ̀; gbogbo awọn ọta rẹ̀ li o nfẹ̀ si.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọ̀nà Rẹ̀ ń gún régé nígbà gbogbo; òun ń gbéraga, òfin Rẹ sì jìnnà sí i; òun kẹ́gàn àwọn ọ̀ta Rẹ̀.