Psalms 10:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó ń rò lọ́kàn ara rẹ̀ pé, kò sí ohun tí ó lè bi òun ṣubú, ati pé ní gbogbo ọjọ́ ayé òun, òun kò ní ní ìṣòro.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O ti wi li ọkàn rẹ̀ pe, A kì yio ṣi mi ni ipò: lati irandiran emi kì yio si ninu ipọnju.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
O wí fún ara Rẹ̀, “Kò si ohun tí ó le mì mí; Inú mi yóò máa dùn nígbà gbogbo èmi kò si ní ní wàhálà.”