Psalms 100:5 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí OLUWA ṣeun; ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí lae, òtítọ́ rẹ̀ sì wà láti ìran dé ìran.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori ti Oluwa pọ̀ li ore; ãnu rẹ̀ kò nipẹkun; ati otitọ rẹ̀ lati iran-diran.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí tí OLÚWA pọ̀ ní oore ìfẹ́ Rẹ̀ sì wà títí láé; àti òtítọ́ Rẹ̀ títí dé gbogbo ayé.