Psalms 101:6 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
N óo máa fi ojurere wo àwọn olóòótọ́ ní ilẹ̀ náà, kí wọ́n lè máa bá mi gbé; ẹni tí ó bá sì ń hu ìwà pípé ni yóo máa sìn mí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Oju mi yio wà lara awọn olõtọ, ki nwọn ki o le ma ba mi gbe: ẹniti o ba nrìn li ọ̀na pipé, on ni o ma sìn mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ojú mi yóò wà lára àwọn olóòtọ́ lórí ilẹ̀, kí wọn kí ó le máa bá mi gbé; ẹni tí o bá ń rìn ọ̀nà pípé òun ni yóò máa sìn mí.