Psalms 101:8 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ojoojumọ ni n óo máa pa àwọn eniyan burúkú run ní ilẹ̀ náà, n óo lé gbogbo àwọn aṣebi kúrò ninu ìlú OLUWA.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Lojojumọ li emi o ma run gbogbo enia buburu ilẹ na; ki emi ki o le ke gbogbo oluṣe buburu kuro ni ilu Oluwa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní ojojúmọ́ ní èmi yóò wá máa pa lẹ́nu mọ gbogbo àwọn ènìyàn búburú ilẹ̀ náà; èmi yóò gé àwọn olùṣe búburú kúrò ní ìlú OLÚWA.