Psalms 102:13 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ìwọ óo dìde, o óo sì ṣàánú Sioni, nítorí ó tó àkókò láti fi ojú àánú wò ó. Àkókò tí o dá tó.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iwọ o dide, iwọ o ṣãnu fun Sioni: nitori igba ati ṣe oju-rere si i, nitõtọ, àkoko na de.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìwọ ó dìde ìwọ o sì ṣàánú fún Síónì, nítorí ìgbà àti ṣe ojú rere sí i; àkókò náà ti dé.