Psalms 102:15 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn orílẹ̀-èdè yóo máa bẹ̀rù orúkọ OLUWA, gbogbo ọba ayé ni yóo sì máa bẹ̀rù ògo rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bẹ̃li awọn keferi yio ma bẹ̀ru orukọ Oluwa, ati gbogbo ọba aiye yio ma bẹ̀ru ogo rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ayé yóò bẹ̀rù orúkọ OLÚWA, gbogbo ọba ayé yóò máa bẹ̀rù ògo Rẹ.