Psalms 102:22 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
nígbà tí àwọn orílẹ̀-èdè bá péjọ tàwọn tọba wọn, láti sin OLUWA.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbati a kó awọn enia jọ pọ̀ ati awọn ijọba, lati ma sìn Oluwa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní ìgbà tí a kó àwọn ènìyàn àti ìjọba pọ̀ láti máa sìn OLÚWA.