Psalms 102:26 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Wọn óo parẹ́ ṣugbọn ìwọ yóo wà títí lae; gbogbo wọn yóo gbó bí aṣọ, o óo pààrọ̀ wọn bí aṣọ; wọn yóo sì di ohun ìpatì.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn o ṣegbe, ṣugbọn Iwọ o duro; nitõtọ gbogbo wọn ni yio di ogbó bi aṣọ; bi ẹ̀wu ni iwọ o pàrọ wọn, nwọn o si pàrọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọn yóò ṣègbé, wọn yóò parun, ṣùgbọ́n ìwọ yóò wà; gbogbo wọn ni yóò gbó bí aṣọ. Bí ẹ̀wù ni ìwọ yóò pààrọ̀ wọn wọn yóò sì di àpatì.