Psalms 102:28 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ọmọ àwọn iranṣẹ rẹ yóo ní ibùgbé; bẹ́ẹ̀ ni arọmọdọmọ wọn yóo fẹsẹ̀ múlẹ̀ níwájú rẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọ awọn iranṣẹ rẹ yio duro pẹ, a o si fi ẹsẹ iru-ọmọ wọn mulẹ niwaju rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọ ìránṣẹ́ Rẹ̀ yóò dúró ní iwájú Rẹ pẹ́; a o sì fi ẹsẹ̀ irú ọmọ wọn sọlẹ̀ ní iwájú Rẹ.”