Psalms 102:8 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn ọ̀tá ń fi mí ṣe yẹ̀yẹ́ tọ̀sán-tòru, àwọn tí wọn ń pẹ̀gàn mi ń fi orúkọ mi ṣépè.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọta mi ngàn mi li ọjọ gbogbo; ati awọn ti nṣe ikanra si mi, nwọn fi mi bu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní ọjọ́ gbogbo àwọn ọ̀ta ológosẹ́ mi ń gàn mí; àwọn tí ń ṣe ìkanra sí mi ń fi orúkọ mi bú.