Psalms 103:18 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó wà lára àwọn tí ó ń pa majẹmu rẹ̀ mọ́, tí wọn sì ń ranti láti pa òfin rẹ̀ mọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Si awọn ti o pa majẹmu rẹ̀ mọ́, ati si awọn ti o ranti ofin rẹ̀ lati ṣe wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Sí àwọn tí ó pa májẹ̀mú Rẹ̀ mọ́ àti àwọn tí ó rántí òfin Rẹ̀ láti ṣe wọ́n.