Psalms 103:22 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹ yin OLUWA, gbogbo iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀, níbi gbogbo ninu ìjọba rẹ̀. Yin OLUWA, ìwọ ọkàn mi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹ fi ibukún fun Oluwa, gbogbo iṣẹ rẹ̀ ni ibi gbogbo ijọba rẹ̀: fi ibukún fun Oluwa, iwọ ọkàn mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Yin OLÚWA, gbogbo iṣẹ́ Rẹ̀ ní ibi gbogbo ìjọba Rẹ̀. Yin OLÚWA, ìwọ ọkàn mi.