Psalms 104:21 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ẹgbọ̀rọ̀ kinniun ń bú fún ìjẹ, wọ́n ń wo ojú Ọlọrun fún oúnjẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ẹgbọrọ kiniun ndún si ohun ọdẹ wọn, nwọn si nwá onjẹ wọn lọwọ Ọlọrun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kìnnìún ń bú ramúramù fún ohun ọdẹ wọn wọ́n sì ń wá oúnjẹ wọn láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run.