Psalms 104:22 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà tí oòrùn bá là, wọn á wọ́ lọ; wọn á lọ dùbúlẹ̀ sinu ihò wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Õrùn là, nwọn kó ara wọn jọ, nwọn dubulẹ ninu iho wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Òòrùn ràn, wọn sì kó ara wọn jọ, wọn padà lọ dùbúlẹ̀ sí ìhò wọn.