Psalms 104:27 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ojú rẹ ni gbogbo wọn ń wò, fún ìpèsè oúnjẹ ní àkókò.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Gbogbo wọnyi li o duro tì ọ; ki iwọ ki o le ma fun wọn li onjẹ wọn li akokò wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn wọ̀nyí ń wò ọ́ láti fún wọn ní oúnjẹ wọn lákòókò Rẹ̀.