Psalms 104:28 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nígbà tí o bá fún wọn, wọn á kó o jọ, nígbà tí o bá la ọwọ́, wọn á jẹ ohun dáradára ní àjẹyó.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Eyi ti iwọ fi fun wọn ni nwọn nkó: iwọ ṣí ọwọ rẹ, a si fi ohun rere tẹ́ wọn lọrùn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí ìwọ bá fi fún wọn, wọn yóò kó o jọ; nígbà tí ìwọ bá là ọwọ Rẹ̀, a tẹ́ wọn lọ́rùn pẹ̀lú ohun rere.