Psalms 105:1 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ẹ dúpẹ́ lọ́wọ́ OLUWA, ẹ pe orúkọ rẹ̀, ẹ fi iṣẹ́ rẹ̀ hàn ní gbogbo orílẹ̀-èdè.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹ fi ọpẹ fun Oluwa? ẹ pè orukọ rẹ̀: ẹ fi iṣẹ rẹ̀ hàn ninu awọn enia.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹ fi ọpẹ́ fún OLÚWA, ké pe orukọ Rẹ̀: Jẹ́ kí a mọ ohun tí ó ṣe láàrin àwọn orílẹ̀ èdè;