Psalms 105:12 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nígbà tí wọ́n kéré ní iye, tí wọn kò tíì pọ̀ rárá, tí wọn sì jẹ́ àjèjì ní ilẹ̀ náà,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbati o ṣe pe kiun ni nwọn wà ni iye; nitõtọ, diẹ kiun, nwọn si ṣe alejo ninu rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí wọn kéré níye, wọn kéré jọjọ, àti àwọn àjòjì níbẹ̀