Psalms 105:13 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
tí wọn ń káàkiri láti orílẹ̀-èdè dé orílẹ̀-èdè, láti ìjọba kan dé òmíràn,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbati nwọn nlọ lati orilẹ-ède de orilẹ-ède, lati ijọba kan de ọdọ awọn enia miran;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọn ń lọ láti orílẹ̀ èdè sí orílẹ̀ èdè, láti ìjọba kan sí òmìrán.