Psalms 105:14 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
kò jẹ́ kí ẹnikẹ́ni ni wọ́n lára, ó bá àwọn ọba wí nítorí wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
On kò jẹ ki ẹnikẹni ki o ṣe wọn ni iwọsi: Nitõtọ, o ba awọn ọba wi nitori wọn;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kò gba ẹnikẹ́ni láàyè láti pọ́n wọn lójú; ó fi ọba bú nítorí tí wọn: