Psalms 105:16 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà kan, ó mú kí ìyàn jà ní ilẹ̀ náà: ó ṣẹ́ ọ̀pá oúnjẹ mọ́ wọn lẹ́nu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Pẹlupẹlu o pè ìyan wá si ilẹ na: o ṣẹ́ gbogbo ọpá onjẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó pe ìyàn sórí ilẹ̀ náà ó sì pa gbogbo ìpèṣè oúnjẹ wọn run;