Psalms 105:20 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ọba ranṣẹ pé kí wọ́n tú u sílẹ̀, aláṣẹ àwọn orílẹ̀-èdè sì dá a sílẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọba ranṣẹ, nwọn si tú u silẹ; ani ijoye awọn enia, o si jọwọ rẹ̀ lọwọ lọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọba ránsẹ́ lọ tú u sílẹ̀ àwọn aláṣẹ ènìyàn tú u sílẹ̀