Psalms 105:22 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
láti máa ṣe olórí àwọn ìjòyè rẹ̀, kí ó sì máa kọ́ àwọn àgbà ìlú ní ìmọ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Lati ma ṣe akoso awọn ọmọ-alade rẹ̀ nipa ifẹ rẹ̀; ati lati ma kọ́ awọn igbimọ rẹ̀ li ọgbọ́n.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gẹ́gẹ́ bí ìfẹ́ Rẹ̀, kí ó máa ṣe àkóso àwọn ọmọ aládé kí ó sì kọ́ àwọn àgbà Rẹ̀ ní ọgbọ́n.