Psalms 105:24 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
OLUWA mú kí àwọn eniyan rẹ̀ pọ̀ sí i, ó sì mú kí wọ́n lágbára ju àwọn ọ̀tá wọn lọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si mu awọn enia rẹ̀ bi si i pipọ̀-pipọ̀; o si mu wọn lagbara jù awọn ọta wọn lọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
OLÚWA, sì mú àwọn ọmọ Rẹ̀ bí síi ó sì mú wọn lágbára jù àwọn ọ̀tá wọn lọ