Psalms 105:25 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ó yí àwọn ará Ijipti lọ́kàn pada, tóbẹ́ẹ̀ tí wọ́n fi kórìíra àwọn eniyan rẹ̀, tí wọ́n sì hùwà àrékérekè sí àwọn iranṣẹ rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O yi wọn li aiya pada lati korira awọn enia rẹ̀, lati ṣe arekereke si awọn iranṣẹ rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó yí wọn lọkàn padà láti korìíra àwọn ènìyàn láti ṣe àrékérekè sí àwọn ìránṣẹ́ Rẹ̀.