Psalms 105:27 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọ́n ṣe iṣẹ́ àmì rẹ̀ ní ilẹ̀ náà, wọ́n sì ṣe iṣẹ́ ìyanu rẹ̀ ní ilẹ̀ Hamu,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn fi ọ̀rọ àmi rẹ̀ hán ninu wọn, ati iṣẹ iyanu ni ilẹ Hamu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọn ń ṣé iṣẹ́ ìyanu láàrin wọn ó ṣe iṣẹ́ ìyanu ní Ámù