Psalms 105:33 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó kọlu àjàrà ati igi ọ̀pọ̀tọ́ wọn, ó sì wó àwọn igi ilẹ̀ wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si lu àjara wọn, ati igi ọ̀pọtọ wọn; o si dá igi àgbegbe wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó lu àjàrà wọn àti igi ọ̀pọ̀tọ́ wọn ó sì dá igi orílẹ̀ èdè wọn.