Psalms 105:35 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
wọ́n jẹ gbogbo ewé tí ó wà ní ilẹ̀ wọn, ati gbogbo èso ilẹ̀ náà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn si jẹ gbogbo ewebẹ ilẹ wọn, nwọn si jẹ eso ilẹ wọn run.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọn sì jẹ gbogbo ewé ilẹ̀ wọn, wọ́n sì jẹ èso ilẹ̀ wọn run