Psalms 105:37 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Lẹ́yìn náà, ó mú àwọn ọmọ Israẹli jáde, tàwọn ti fadaka ati wúrà, kò sì sí ẹnikẹ́ni ninu ẹ̀yà kankan tí ó ṣe àìlera.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si mu wọn jade, ti awọn ti fadaka ati wura: kò si si alailera kan ninu ẹ̀ya rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó mú Ísírẹ́lì jáde ti òun ti fàdákà àti wúrà, nínú ẹ̀yà Rẹ̀ kò sí aláìlera kan.