Psalms 105:38 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Inú àwọn ará Ijipti dùn nígbà tí wọ́n jáde, nítorí ẹ̀rù àwọn ọmọ Israẹli ń bà wọ́n.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Inu Egipti dùn nigbati nwọn lọ: nitoriti ẹ̀ru wọn bà wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Inú Éjíbítì dùn nígbà tí wọn ń lọ, nítorí ẹ̀rù àwọn Ísírẹ́lí ń bá wọ́n.