Psalms 106:16 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà tí wọ́n ṣe ìlara sí Mose ninu ibùdó, ati sí Aaroni, ẹni mímọ́ OLÚWA.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn ṣe ilara Mose pẹlu ni ibudo, ati Aaroni, ẹni-mimọ́ Oluwa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nínú ibùdó ni wọ́n ṣe ìlara Mósè pẹ̀lú Árónì, ẹni tí ó jẹ́ mímọ́ sí OLÚWA.