Psalms 106:23 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí náà ni ó ṣe wí pé òun yóo pa wọ́n run, bí kì í bá ṣe ti Mose, àyànfẹ́ rẹ̀, tí ó dúró níwájú rẹ̀, tí ó sì ṣìpẹ̀, láti yí ibinu OLUWA pada, kí ó má baà pa wọ́n run.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina li o ṣe wipe, on o run wọn, iba máṣe pe Mose, ayanfẹ rẹ̀, duro niwaju rẹ̀ li oju-ẹya na, lati yi ibinu rẹ̀ pada, ki o má ba run wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bẹ́ẹ̀ ní, ó sọ wí pé oun yóò pa wọ́n run bí kò ba ṣe tí Mósè, tí ó yàn, tí ó dúró níwájú ẹ̀yà náà tí ó pa ìbínú Rẹ̀ mọ́ láti má pa wọ́n run mọ́