Psalms 106:24 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọn kò bìkítà fún ilẹ̀ dáradára náà, wọn kò sì ní igbagbọ ninu ọ̀rọ̀ OLUWA.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitõtọ, nwọn kò kà ilẹ didara nì si, nwọn kò gbà ọ̀rọ rẹ̀ gbọ́:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà, wọn kẹ́gàn ilẹ̀ dídára náà wọn kò gba ilérí Rẹ̀ gbọ́.