Psalms 106:25 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọ́n ń kùn ninu àgọ́ wọn, wọn kò sì fetí sí ohùn OLUWA.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn nwọn nkùn ninu agọ wọn, nwọn kò si feti si ohùn Oluwa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọn ń kùn nínú àgọ́ wọn wọn kò sì gbọ́ràn sí OLÚWA.