Psalms 106:26 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí náà, ó gbé ọwọ́ sókè, ó búra fún wọn pé òun yóo jẹ́ kí wọ́n kú sí aṣálẹ̀,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina li o ṣe gbé ọwọ rẹ̀ soke si wọn, lati bì wọn ṣubu li aginju:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bẹ́ẹ̀ ni ó gbé ọwọ́ Rẹ̀ sókè sí wọn kí òun le jẹ́ kí wọn ṣubú nínú ihà,