Psalms 106:27 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
ati pé òun yóo fọ́n àwọn ìran wọn káàkiri àwọn orílẹ̀-èdè.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Lati bì iru-ọmọ wọn ṣubu pẹlu lãrin awọn orilẹ-ède, ati lati fún wọn ka kiri ni ilẹ wọnni.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Láti jẹ́ kí àwọn ọmọ Rẹ̀ ṣubú lára orílẹ̀ èdè láti fọ́nu wọn káàkiri lórí ilẹ̀.