Psalms 106:28 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọ́n da ara wọn pọ̀ mọ́ Baali ti Peori, wọ́n sì ń jẹ ẹbọ tí wọ́n rú sí òkú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn da ara wọn pọ̀ pẹlu mọ Baali-Peoru, nwọn si njẹ ẹbọ okú.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọn dá ara wọn pọ̀ mọ́ Baali-Péórù, wọn sì ń jẹ ẹbọ ti a rú sí àwọn òkú òrìṣà