Psalms 106:3 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ayọ̀ ń bẹ fún àwọn tí ń ṣe ẹ̀tọ́, àwọn tí ń ṣe ohun tí ó tọ̀nà nígbà gbogbo.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ibukún ni fun awọn ti npa idajọ mọ́, ati ẹniti nṣe ododo ni igbagbogbo.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìbùkún ni fún àwọn tí ń pa ìdájọ́ mọ́? Ẹni tí tí ń ṣe ohun tí ó tọ́