Psalms 106:30 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nígbà náà ni Finehasi dìde, ó bẹ̀bẹ̀ fún wọn, àjàkálẹ̀ àrùn sì dáwọ́ dúró.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni Finehasi dide duro, o si ṣe idajọ: bẹ̃li àrun nla na si dá.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n Fínéhásì dìde láti dá sí i, àjàkálẹ̀-àrùn náà sì dáwọ́ dúró lọ́gán