Psalms 106:32 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọ́n mú OLUWA bínú lẹ́bàá omi Meriba, wọ́n sì fi tiwọn kó bá Mose,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn bi i ninu pẹlu nibi omi Ijà, bẹ̃li o buru fun Mose nitori wọn:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Níbi omi Méríbà, wọn bí Ọlọ́run nínú, ohun búburú wá sí orí Mósè nítorí wọn.