Psalms 106:34 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọn kò pa àwọn eniyan ilẹ̀ náà run, gẹ́gẹ́ bí OLUWA ti pa á láṣẹ fún wọn,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn kò run awọn orilẹ-ède na, niti ẹniti Oluwa paṣẹ fun wọn:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọn kò pa àwọn ènìyàn run gẹ́gẹ́ bí Ọlọ́run tí sọ fún wọn,