Psalms 106:35 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
ṣugbọn wọ́n dara pọ̀ mọ́ àwọn orílẹ̀-èdè náà, wọ́n sì kọ́ ìṣe wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn nwọn da ara wọn pọ̀ mọ́ awọn keferi, nwọn si kọ́ iṣẹ wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n wọn dàpọ̀ mọ́ àwọn orílẹ̀ èdè, wọ́n sì gbà láti ṣe bí àṣà wọn