Psalms 106:38 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọ́n ta ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ sílẹ̀, àní, ẹ̀jẹ̀ àwọn ọmọkunrin, ati ti àwọn ọmọbinrin wọn, tí wọ́n fi bọ àwọn oriṣa ilẹ̀ Kenaani; wọ́n sì fi ẹ̀jẹ̀ sọ ilẹ̀ náà di aláìmọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn si ta ẹ̀jẹ alaiṣẹ̀ silẹ, ani ẹ̀jẹ awọn ọmọkunrin wọn ati ti awọn ọmọbinrin wọn, ti nwọn fi rubọ si ere Kenaani: ilẹ na si di aimọ́ fun ẹ̀jẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọn ta ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ sílẹ̀. Ẹ̀jẹ̀ àwọn ọmọkùnrin àti àwọn ọmọbìnrin wọn. Wọn fi wọ́n rúbọ sí ère Kénánì, ilẹ̀ náà sì di àìmọ́ fún ẹ̀jẹ̀