Psalms 106:39 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí náà, wọ́n fi ìṣe wọn sọ ara wọn di aláìmọ́, wọ́n sì sọ ara wọn di alágbèrè.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn si fi iṣẹ ara wọn sọ ara wọn di alaimọ́, nwọn si ṣe panṣaga lọ pẹlu iṣẹ wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọn si fi ìṣe ara wọn sọ ara wọn di aláìmọ́, wọ́n sì ṣe panṣágà lọ pẹ̀lú iṣẹ́ wọn.