Psalms 106:4 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ranti mi, OLUWA, nígbà tí o bá ń ṣí ojurere wo àwọn eniyan rẹ. Ràn mí lọ́wọ́ nígbà tí o bá ń gbà wọ́n là.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Oluwa, fi oju-rere ti iwọ ni si awọn enia rẹ ṣe iranti mi: fi igbala rẹ bẹ̀ mi wò.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Rántí mi, OLÚWA, Nígbà tí ó bá fi ojú rere Rẹ̀ hàn, wá sí ìhà mi nígbà tí ìwọ bá gbà wọ́n,