Psalms 106:40 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà náà ni inú bí OLUWA sí àwọn eniyan rẹ̀, ó sì kórìíra àwọn ẹni ìní rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina ni ibinu Oluwa ṣe ràn si awọn enia rẹ̀, o si korira awọn enia ini rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà OLÚWA bínú sí àwọn ènìyàn Rẹ̀ ó sì kórìíra àwọn ènìyàn Rẹ̀