Psalms 106:41 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó fi wọ́n lé àwọn orílẹ̀-èdè mìíràn lọ́wọ́, títí tí àwọn tí ó kórìíra wọn fi jọba lé wọn lórí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si fi wọn le awọn keferi lọwọ; awọn ti o korira wọn si ṣe olori wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó sì fà wọ́n lé àwọn orílẹ̀ èdè lọ́wọ́, àwọn ọ̀tá wọn sì jọba lórí wọn.