Psalms 106:43 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ọpọlọpọ ìgbà ni ó gbà wọ́n sílẹ̀, ṣugbọn wọ́n ti pinnu láti máa tàpá sí i, OLUWA sì rẹ̀ wọ́n sílẹ̀ nítorí ẹ̀ṣẹ̀ wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Igba pupọ li o gbà wọn; sibẹ nwọn fi ìmọ wọn mu u binu, a si rẹ̀ wọn silẹ nitori ẹ̀ṣẹ wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní ọ̀pọ̀ ìgbà òun gbà wọ́n, Ṣíbẹ̀ wọ́n si ń ṣọ̀tẹ̀ sí ì wọ́n sì sòfò dànù nínú ẹ̀ṣẹ̀ wọn.